Bí O Se Le Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Àdáni Pẹ̀lú Owó Gamme
Got something to say to this podcast? Send a voicemail, and you might hear yourself on the next episode! Ninu ẹ̀dà eto "Ọrọ Ìṣòwò" yii, Ọgbẹni Wale Kuku (ti o jẹ olutunyin ati eniyan to n ṣe agbeyewo imọtoye lori eto iduma re) sọrọ lori bi a ṣe le bẹrẹ iṣẹ àdáni pẹ̀lú owó gọọmẹ. O se alaye lori bii a ṣe le bẹrẹ iṣẹ adani diẹ-diẹ gẹgẹbi iṣẹ onírúurú sorosoro, tita awọn nkan kekere bii biscuit ati sinṣin, tabi ṣiṣe awọn iṣẹ kan ti o le mu owo wọle. Ó tún jíròrò lori pataki lilo ero ayelujara ati awujọ (social media) lati gbe iṣẹ ga, pẹlu imọran pe ki a kọkọ kọwe tabi gbero daradara ki a to bẹrẹ iṣẹ kankan.